Home Posts tagged Alhaji Adeniyi Ọdekunle
Yoruba

Ilé Isẹ́ Radio Nigeria Fẹ́ẹ̀ Kí Àlékún Bá Ìdánilẹ̀kọ Fáwọn Òsìsẹ́ Rẹ̀

Ilé isẹ́ Radio Nigeria, FRCN, ti tẹnumọ́ pàtàkì sísàmúlò àsà wíwo àwòkọ́se òun síse ìdánilẹ́kọ lábẹ́lé kólè fi kún akitiyan àwọn òsìsẹ́ kí wọ́n le jáfáfá si lẹ́nu isẹ́. Ọga àgbà lẹ́ka ìròyìn àti ọ̀rọ̀ tónlọ fúnlé isẹ́ Radio Nigeria, ẹkùn Ìbàdàn Alàgbà Adenrele Ajisefinni ló sọ̀rọ̀ náà nílu Continue Reading