O se pàtàkì kawon eeyan awujo maa fifehan sawon to ba ti Fara soko logba èwòn rí, lónà àti maa jeki won tun pass sirufe igbesiaye tiwon n gbe tele, eyi to sokunfa biwon se dogba èwòn. Èyí lafenuko àwon olukopa lori ètò olosoose Ile ise wa kan lédè gèésì tapeni focal point. Agbenuso ibudo Continue Reading