Home Posts tagged Arábìnrin Folukẹ Ayọọla
Yoruba

Alága Ẹgbẹ́ Ọ̀dọ́ Pè Fún Atilẹyin Àwọn Ọ̀dọ́ Lágbo Òsèlú

Wọn ti gba awọn ọ̀dọ́ ilẹ̀yí níyànjú pé kí wọ́n máà kópa tó jọjú nínú ètò òsèlú nípa darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òsèlú tó bá wù wọ́n, kí wọ́n sì ríì dájú pé wọ́n gba ìwé ìdìbò alálòpẹ́. Alága ẹgbẹ́ àwọn ọ̀dọ́ nílẹ̀yí ẹ̀ka tìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Ọ̀gbẹ́ni Abdulsalam Olusẹgun ló sọ̀rọ̀ ìyànjú yi nínú ọ̀rọ̀ ìkíni Continue Reading