Home Posts tagged àwọn darandaran
Yoruba

Ilé ìgbìmọ̀ asòfin kejì pè fún ìfikùnlukùn láti yanjú áàwọ̀ àwọn darandaran àtàwọn agbègbè tón gbawọn lálejò

Adarí ilé ìgbìmọ̀ asòfin kejì, ọ̀gbéni Fẹmi Gbajabiamila ti pè fún ìpàdé kan, lórí ọ̀nà láti wójùtú sọ́rọ̀ àwọn tó ń wáyé láàrin àwọn darandaran àtàwọn agbègbè tón gbawọn lálejò lápá àríwá orílẹ̀èdè yíì, kó tó di pé ọ̀rọ̀ burú kọjá bó se yẹ. Ìlú Abuja lọ̀gbéni Gbajabiamila ti sọ̀rọ̀ yíì di Continue Reading