Home Posts tagged àwọn lọ́ba-lọ́ba
Yoruba

Ilé asòfin àgbà pèfún fífun àwọn lọ́ba-lọ́ba ni ojúse

Bí orílẹ̀èdè Nàijírìa yóò báà lọ́wọ́ ìpènìjà tó ńkojú, ẹ̀ka ètò àbò rẹ̀, àwọn lọ́ba-lọ́ba gbọ́dọ̀ jẹ́ fífún ni ojúse níbamu pẹ̀lú òfin orílẹ̀èdè yíì. Èyí jẹ́ àfẹnukòadarí ilé-ìgbìmọ̀ asòfin àpapọ̀ ilẹ̀ yíì, Amad Lawan níbi ìpàdé kan tówà yẹ́ẹ̀ lófìsì rẹ̀ nílu Abuja. Adarí ilé sàlàyé pé, fífún Continue Reading