Awon akopa lori eto ileese Radio Nigeria, Ibadan tiwon pe lede geesi ni focal Point n fe ki ajosepo to munadoko wa lori didabobo ayika lati dena ayipada oju ojo. Awon akopa lori eto, lo soro yi lasiko ti won soro lori ayajo ojo moniyan lagbaye, pelu alaye pe ipa ti omoniyan nko lori ayika, […]Continue Reading