Home Posts tagged Awujo
Yoruba

Gómìnà Makinde pè fún ìkúnlọ́wọ́ fáwọn tó kù diẹ káato fún láwùjọ

Gómìnà ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ onímọ̀ ẹ̀rọ Seyi Makinde ti késí àwọn aráàlu, àwọn ilé isẹ́, àwọn ẹlẹ́yinjú anu, lájọlájọ àtàwọn min tọ́rọnkàn lórí síse ìkúnlọ́wọ́ fúnjọba fún ìgbáyégbádùn àwọn tókùn diẹ káàto fún nípinlẹ̀ yí. Gómìnà pe ìpè náà lásìkò ayẹyẹ fífa ilé gbe àwọn ọkùnrin ohun ófìsì tódi Continue Reading
Yoruba

Àjọ SON, kìlọ̀ fáwọn iléesẹ́ tó ń pèsè irin tútù lórí àmójútó irin-isẹ́ nítorí àwùjọ

Àjọ tó ń rí sí ìpeniye ǹkan ìlò nílẹ̀ Níajírìa SON, ti sèkìlọ̀ fáwọn iléésẹ́ tó ń pèsè irin pé kí wọ́n mójútó àwọn irin-isẹ́ tí wọ́n ńlò fún ìpèsè irin. Olùdarí àgbà àjọ SON, ọ̀gbẹ́ni Farouk Salim tó sípayá ọ̀rọ̀ yí níbi àpéjọpọ̀ kan tó wáyé nílu Abuja sọ́ọ̀ di mímọ̀ pé àjọ náà […]Continue Reading