Home Posts tagged Aya Gómìnà
News Yoruba

Àwọn Aya Gómìnà Ké Gbàjerè Lórí Ètò Àbò Tó Mẹ́hẹ

Àwọn aya Gómìnà lábẹ́ ẹgbẹ́ aya Gómìnà nílẹ̀ Nàijírìa ti bu ẹnu àtẹ́lu bí ètò àbò seń mẹ́hẹ yíká ilẹ̀ yí. Bákanà ni wọ́n fi àidúnú hàn lórí bí isẹ́ òn òsì seń gogò si, àinísẹ́ lọ́wọ́ àwọn èyàn nílẹ̀ yí tófimọ́ àwọn ìwà ìbàjẹ́ miràn. Alága ẹgbẹ́ náà, Arábìnrin Bisi Fayẹmi títúnse aya Gómìnà […]Continue Reading