
Awon adari esin to kesi ijoba apapo lati wa ona topin yoo ri ba, igbese bawon darandaran atawon jaguda se nlo ohun ija-oloro fi koolu awon alaise. Sultan Sokoto Alhaji Muhammadu Sa’ad, Abubaka keta ati Aare egbe awon omoleyin Kristi, CAN, Eniowo Samson Ayokunle tiwon dijo lewaju igbimo to nrisi oro esin NIREC bere fun […]Read More...