Ìjọba àpapọ̀ ti setán láti gba owó tó wọ ẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ milliọnu naira tí wọ́n sesi san fun àwọn Dókítà onímọ̀ ìsègùn tó lé ní ẹdẹgbẹta níye yíká orílẹ̀ èdè yí. Alákoso fọ́rọ̀ isẹ́ àti ìgbanisísẹ́ Sẹnatọ Chris Ngige ló sọ̀rọ̀ yí di mímọ́ lásìkò tón dáhun ìbere látọ̀dọ̀ àwọn akọ̀ròyìn nílu Abuja. Continue Reading
Egbe awon Dokita, to ngba imo kun imo, lati di akosemose, sope awon yoo gunle iyanselodi alainigbedeke, lojobo tijoba apapo baa kuna lati dahun si ibere won. Ninu atejade eyi ti won fisita leyin ipade egbe nee nilu Abuja, Aare egbe ohun, Dokitia Uyilawa Okhauaihesuyi ati akowe agba, Dokita Jerry Isogun fowosi bere fun sisan […]Continue Reading