Home Posts tagged Dokita Yetunde Adeniyi
Yoruba

Awon Toro Kan Pe Fun Amojuto To Peye F’awon Ewe

Síse àmúgbòrò ẹ̀ka iléèsẹ́ ìjọba tó n rí sí ìgbáyégbádùn aráàlu nípinlẹ̀ ọ̀yọ́ yóò mú àdínkù bá síse ọmọdé nísekúse láwùjọ. Èyí lèrò àwọn tó kópa lórí ètò focal point lédè gẹ́ẹ̀sì, níléèsẹ́ wa premier F.M. Àwọn tó kópa lórí ètò náà tẹnumọ pé kíjọba túnbọ̀ pèsè irinsẹ́ fáwọn òsìsẹ́ ẹ̀ka tó n Continue Reading