Egbe awon osise NLC, ti fesun kana won oloselu atawon ebi won fesun kiko oro ile yi fun arawon. Aare egbe NLC, Ogbeni Ayuba Wabba, nibi oro ayeye ogota odun ominira ile yi tokasi pe, orileede Nigeria nikan loku larin awon orileede to n fi epo robi sowo sile okere to ko ti ni ebu […]Continue Reading
Ijoba Ipinle Ogun ti kesi awon asoju egbe osise to wa nipinle naa pe ki won pada senu ifikunlukun pelu Ijoba lati fi wa ojutu si ibeere won. Ninu atejade ninu Abeokuta ni akowe Ijoba Ipinle naa Ogbeni Tokunbo Talabi ti soro di mimo pea won asoju egbe osise lo kuro nibi iforowero naa patapata […]Continue Reading