Home Posts tagged ètò ìbáraẹnisọ̀rọ̀
Yoruba

Àjọ NCC setán láti sàfikún ibùdó ìsẹ̀lẹ̀ pàjáwìrì lẹ́ka ètò ìbáraẹnisọ̀rọ̀

Àjọ tón rí sétò ìbáraẹnisọ̀rọ̀ nílẹ̀ yíì, NCC, sọ pé òun sisẹ́ takuntakun láti sàgbékalẹ̀ àwọn ibùdó tí yóò máà rísí ìsẹ̀lẹ̀ pàjáwìrì lẹ́ka ètò ìbáraẹnisọ̀rọ̀ láwọn ìpèníjì níbití kò ti sàwọn ohun èlò kankan lọ́wọ́lọ́wọ́ báyíì. Igbákejì alága àjọ NCC, ọ̀gbẹ́ni Umar Danbatta ló sọ̀rọ̀ ytíì di Continue Reading