Awon elesin abalaye nipinle Oyo ti gbosuba fun, Gomina Ipinle Osun Ogbeni Gboyega Oyetola lori igbese kikede isinmi lenuse lati samin ayajo ojo isese nipinle. Ninu atejade eyi ti alaga egbe awon elesin abalaye teka ipinle Oyo Ogbeni Adefabi Fadiran ati akowe, omowe Fakayode Fatunde fisita nilu Continue Reading
Gomina ipinle Osun, Ogbeni Adegboyega Oyetola ti so di mimo pe ona kan soso tile yi fi lee wa ojutu is ipenija eto aabo ni pinpin agbara nilana ile ise olopa. Gomina Oyetola soju oro yi lede nilu Abuja pelu alaye wipe awon ileese agbofinro ile yi lo je pe ojukan ni agbara won sodo […]Continue Reading