Home Posts tagged Ilé asòfin ìpínlẹ̀ Ọyọ gbé ìgbésẹ̀ lórí ìpèsè iná ọba
Yoruba

Ilé asòfin ìpínlẹ̀ Ọyọ gbé ìgbésẹ̀ lórí ìpèsè iná ọba

Ìlé asòfin ìpínlẹ̀ Ọyọ ti ké sálákoso fọ́rọ̀ ohun àmúsagbára, ọ̀gbẹ́ni  Seun Ashamu, àwọn òsìsẹ́ ilé-isẹ́ tón rí sọ́rọ̀ ohun àmúsagbára àti ìgbìmọ̀ tó ń rí sọ́rọ̀ iná ọba láwọn agbègbè ìgbèríko nípinlẹ̀ Ọyọ láti wá farahàn níwájú ilé, lórí bíwọ́n se páwọn ẹ̀rọ afúnálágbára Transformer kan Continue Reading