-
Ilé Asòfin ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ buwọ́lu àbá ètò ìsúná ọdún 2021
Ilé ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ti so àbá ètò ìsúná ọdún 2021 tí iye rẹ̀ jẹ́ ọ̀ọdúnrún ófín diẹ billiọnu naira. Èyí ló wáyé níbamu pẹ̀lú àbọ̀ tígbìmọ̀ tẹkótó ilé fọ́rọ̀ tóníse pẹ̀lú àsùnwọ̀n owólu, ètò ìsúná àtàatò gbogbo gbékawájú ilé lákokò ìjóko rẹ̀. A ó rántí pé, ní ǹkan bí ọ̀sẹ̀ diẹ sẹ́yìn, ni…
-
Ilé asòfin ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ fẹ́kí ilé-ẹ̀kọ́ alájẹsẹ́kù bẹ̀rẹ̀ isẹ́ ní pẹrẹu
Ilé ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ti bèèrè fun yiyan ìgbìmọ̀ alábojútó fún ilé-ìwé tó ń rí sétò ẹ̀kọ́ alájẹsẹ́ku àtẹ̀kọ́ nípa ìdókóòwò, tó wà nílu Ìlọra níjọba ìbílẹ̀ Afijio nípinlẹ̀ yíì láti lè jẹ́ kó bẹ̀rẹ̀ isẹ́ ní pẹrẹ u. Èyí ló wáyé níbamu pẹ̀lú àbá kan tóníse pẹ̀lú ìdí tófí se pàtàkì kíwọ́n sàmúlò…