Home Posts tagged Ilé ẹjọ́ tó gajù ti da ẹjọ́ ẹgbẹ́ òsèlú PDP tí ó tako ìjáwé olúborí
Yoruba

Ilé ẹjọ́ tó gajù ti da ẹjọ́ ẹgbẹ́ òsèlú PDP tí ó tako ìjáwé olúborí

Ilé ẹjọ́ tó gajù ti da ẹjọ́ òsèlú PDP, àti olùdíje fún ipò àarẹ Atiku Abubakar nù, fún títako ìjáwé olúborí àarẹ Muhammadu Buhar i nínú ètò ìdìbò èyí tí ó wáyé nínú osù kejì ọdún 2019. Atiku àti ẹgbẹ́ òsèlú rẹ̀ tako ìdájọ́ tí onídajọ́ Mohammed Garba gbékalẹ̀ láti fi ìjáwé olúborí àarẹ Muhammadu Continue Reading