Home Posts tagged ilé-ẹ̀kọ́ alájẹsẹ́kùn
Yoruba

Ilé asòfin ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ fẹ́kí ilé-ẹ̀kọ́ alájẹsẹ́kù bẹ̀rẹ̀ isẹ́ ní pẹrẹu

Ilé ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ti bèèrè fun yiyan ìgbìmọ̀ alábojútó fún ilé-ìwé tó ń rí sétò ẹ̀kọ́ alájẹsẹ́ku àtẹ̀kọ́ nípa ìdókóòwò, tó wà nílu Ìlọra níjọba ìbílẹ̀ Afijio nípinlẹ̀ yíì láti lè jẹ́ kó bẹ̀rẹ̀ isẹ́ ní pẹrẹ u. Èyí ló wáyé níbamu pẹ̀lú àbá kan tóníse pẹ̀lú ìdí tófí se pàtàkì kíwọ́n Continue Reading