Home Posts tagged Ilé ẹ̀kọ́ gbogbonìse ìlú’bàdàn
Yoruba

Ilé ẹ̀kọ́ gbogbonìse ìlú’bàdàn lájọsepọ̀ pẹ̀lú agbègbè tó yíká lórí dídẹ́kun ìtànkálẹ̀ àrùn covid 19

Gẹ́gẹ́bí ara akitiyan láti gbaradì fún sísí iléwe padà nípinlẹ̀ ọ̀yọ́ ìgbìmọ̀ aláse ilé-ẹ̀kọ́ gbogbonìse ìbàdàn ti se ìpàdé pọ̀ pẹ̀lú àwọn bàbá onílé tó wà lágbègbè ilé ẹ̀kọ́ ọ̀hún. Ìpàdé náà ni ówáyé láti jíròrò lórí ọ̀nà tí wọ́n yo fi dẹ́kun ìtànkálẹ̀ àrùn covid 19, ètò àbò tó mẹ́hẹ àti wiwọ Continue Reading