Home Posts tagged Ilé ìgbìmọ̀ asòfin kejì
News Yoruba

Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Kejì Bèrè Fún Àgbékalẹ̀ Òfin Tí Yóò Dènà Kíkó Àwọn Ǹkan Ìjagun Wọlé

Ilé ìgbìmọ̀ asòfin kejì ti ńgbé ìgbésẹ̀ láti fòfinde kíkó àwọn ohun ìjagun wọ orílẹ̀dè yíì. Àbá òfin ọ̀hún tó wọ́n ti kà fún igbákejì niwọ̀n ti fi sọwọ́ sí ìgbìmọ̀ tí tẹkótó ilé fọ̀rọ̀ ìlànà àti àfẹnukò láti gbéyẹ̀wò. Ìgbìmọ̀ tẹkótó ilé fọrọ ìlànà àtafẹnukò náà sèpàdé èyítí ọ̀mọ̀wé Nicholas Continue Reading
Yoruba

Ilé ìgbìmọ̀ asòfin kejì pè fún ìfikùnlukùn láti yanjú áàwọ̀ àwọn darandaran àtàwọn agbègbè tón gbawọn lálejò

Adarí ilé ìgbìmọ̀ asòfin kejì, ọ̀gbéni Fẹmi Gbajabiamila ti pè fún ìpàdé kan, lórí ọ̀nà láti wójùtú sọ́rọ̀ àwọn tó ń wáyé láàrin àwọn darandaran àtàwọn agbègbè tón gbawọn lálejò lápá àríwá orílẹ̀èdè yíì, kó tó di pé ọ̀rọ̀ burú kọjá bó se yẹ. Ìlú Abuja lọ̀gbéni Gbajabiamila ti sọ̀rọ̀ yíì di mímọ̀ pẹ̀lú àlàyé […]Continue Reading