Home Posts tagged ìlésẹ́ apínáká
Yoruba

ìjọba àpapọ̀ fẹ́ fòpinsí bí ìlésẹ́ apínáká se n bu owó iná fáwọn oníbarà

Àarẹ orílẹ̀dè yíì, Muhammadu Buhari ti tẹnumọ́ ìpinnu ìjọba tó wà lóde báyíì láti fòpinsí báwọn ilé-isẹ́ apínná ká se máà ńbu owó láibítà fáwọn oníbarà wọn nílẹ̀ Nìajírìa. Àarẹ Buhari tó sọ̀rọ̀ yíì di mímọ̀ nílu Abuja, tó sì sàlàyé pé, ìsèjọba òun yóò ridájú pé, iye iná ọba táwọn ọmọ orílẹ̀dè Continue Reading