-
Ajo eleto idibo se ileri ibo ti ko leja nba-kan ninu ni ipinle ekiti
Ajo eleto idibo nile yi inec, ti so pe gbogbo ipa to wa ni ikawo re ni yoo sa lati se to idibo ti koni eja nba kan nu ni ipinle ekiti . Alakoso fun ajo inec lekun iwo orun gusu omowe adekunle ogunmola lo so oro yii ni ilu ado – ekiti nigbati ohun…
-
Gomina Fayemi Pase Ayewo Arun Covid-19 Fawon Akeko N’ipinle Ekiti
Gomina ipinle Ekiti, Omowe Kayode Fayemi ti pase ayewo arun COVID-19, awon oluko atawon akeko kokan lati mu adinku ba itankale aarun COVID-19 n’ipinle naa. Gomina Fayemi ninu oro re lori afefe fawon eeyan, tokasi pe igbese ayewo arun, ti safihan opo arun COVID-19, to si sope igbese naa yoo tan de awon ile-eko. O…
-
Ayewo Fihan pe Gomina Ipinle Ekiti ti ni Arun Covid-19
Gomina ipinle Ekiti, Omowe Kayode Fayemi ni ayewo ti fidi e mu’le pe oun ni arun Coronavirus. Gomina Fayemi lo je koro yi di mimo lori opo ero ayelujara abeyefo re, pe ayewo eleeketa ti won se fun ni abajade re so pe oun ni arun naa lana. Gomina loti lo y’ara re soto fun…