Home Posts tagged ìpínlẹ̀ Èkó
News Yoruba

Ọwọn Gógó Owó Ilé Ìwé Ti Fa Kíkó Kúrò Àwọn Akẹ́kọ Nílé Ẹ̀kọ́ Aládani Ìpínlẹ̀ Èkó Látọwọ́ Àwọn Òbí Àtalágbátọ́

Àwọn òbí àti alágbàtọ́ kan ti wọ́n ko lágbára àti san owó ilé ẹ̀kọ́ tó di ọ̀wọ́ngógó ti bẹ̀rẹ̀ síní mú àwọn ọmọ wọn kúrò láwọn ilé ẹ̀kọ́ aládani tón bẹ nípinlẹ̀ Èkó. Ìròyìn fidiẹ múlẹ̀ pé àwọn òbí tọ́rọ̀ kan àti alágbàtọ́ ni wọ́n ńkó àwọn ọmọ wọn lọ sí ilé ẹ̀kọ́ ìjọba. Àwọn […]Continue Reading
Yoruba

Ìpínlẹ̀ Èkó ti gbé àwọn orílẹ̀ èdè mẹ́rìnlá sábẹ́ àmójútó láti dènà ìtànkálẹ̀ ẹ̀yà àrùn covid tuntun

Gẹ́gẹ́bí ara ọ̀nà láti dènà kí àrùn covid 19 tuntun bẹ́ sílẹ̀, ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó ti fi àwọn orílẹ̀ èdè mẹ́rìnlá kan sábẹ́ àmójútó tó péye. Alákoso fétò ìlera nípinlẹ̀ Èkó, ọ̀jọ̀gbọ́n Akin Abayọmi, ló sọ̀rọ̀ yí lásìkò tón bá àwọn akọ̀ròyìn sọ̀rọ̀, óní ìgbésẹ̀ yi ló se pàtàkì lẹ́yìn tí wọ́n sàwárí ẹ̀yà àrùn […]Continue Reading
Yoruba

Gómìnà alágbádá àkọ́kọ́ fún ìpínlẹ̀ Èkó, Lateef Jakande jáde láyé

Gómìnà alágbádá àkọ́kọ́ fún ìpínlẹ̀ Èkó, àlhájì Lateef Kayọde Jakande ti jáde láyé. Alákoso fọ́rọ̀ isẹ́ òde tẹ́lẹ̀ ọ̀ún ló kú lówurọ̀ òní nílu Èkó léni ọfún mọ́kànléláàdọ́run. Àlhájì Jakande ló jẹ́ Gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó láàrin ọjọ́ kini osù kẹwa ọdún 1979 àti ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n osù kejìlá ọdún 1983 lábẹ́ ẹgbẹ́ òsèlú Unity Party of […]Continue Reading