Home Posts tagged ípnlẹ̀ Ògùn
Yoruba

Ilé Asòfin Ìpínlẹ̀ Ògùn pè fún àtúntò òfin ìjọba ìbílẹ̀.

Ilé asòfin ìpínlẹ̀ Ògùn ti sọ́ọ̀ di mímọ̀ pé, àtúnse òfin ìjọba ìbílẹ̀ tí wọ́n ń lò lọ́wọ́ nípinlẹ̀ náà yóò se ìrànwọ́ lórí ìmúpadàbọ̀sípò ìlànà ìsèjọba ìbílẹ̀ nípinlẹ̀ náà. Èyí ni wọ́n sọ pé yóò mọriiri àwọn òsìsẹ́ ìjọba tí yo si mú igbayegbadun wọn lọkunkundun. Adarí ilé asòfin ìpínlẹ̀ náà, Continue Reading