Kòdín ní ẹgbẹ̀rún mẹ́ta èèyàn ló ti jànfàní ètò ìrónilágbára ti ó fisi aya Gómìnà ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́, Arábìnrin Tamunọminini Makinde gbé kalẹ̀ nípinlẹ̀ yí. Àwọn tó jànfàní ètò náà ni wọ́n kójọ jákèjádò ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́tàlélọ́gbọ̀n tón bẹ nípinlẹ̀ ọ̀yọ́. Ètò ìrónilágbára náà ló wáyé láwọn ìlú ní ẹkùn Continue Reading
Kodin ni opo bi eedegberin, 700, ti janfani eto ironilagbara ti ofisi aya gomina ipinle Oyo, Arabinrin Tamunomini Makinde gbe kale fun mimu iderun bawon. Nigba to n soro nibi eto ohun to waye nileegbe ijoba to wa Lagodi, nily Ibadan, Arabinrin Makinde wa gba awon opo niyanju lati sise lori diduro lori owo arawon […]Continue Reading