Home Posts tagged Iyanselodi
News Yoruba

Àwọn Osise Tó Wà Láwọn Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Àti Ògùn Ti Gùnlé Ìyansẹ́lódì Aláinigbèdéke.

Gbogbo ǹkan ló pakasọ lówurọ òní nílé ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ nítorí bágbe àwọn òsìsẹ́ ẹ̀ka ilé ìgbìmọ̀ asòfin nípinlẹ̀ yíì, se gba ẹnu ọ̀nà àbáwọlé sílé ìgbìmọ̀ asòfin náà tìpa. Ìgbésẹ̀ yíì ló wáyé níbamu pelu olùfẹ̀hóhàn tíwọ́n gùnlẹ̀ èyí tíwọ́n fin bèèrè fómìnira ètò ìsúná fáwọn asòfin ọ̀hún. Oníròyìn ilé-isẹ́ Radio Nigeria, tó […]Continue Reading
Yoruba

Àwọn Akẹ́kọ Ilé Ẹ̀kọ́ Gíga Nípinlẹ̀ Ọ̀yọ́ Wọ́de Lórí Ìyansẹ́lódì Ẹgbẹ́ ASUU

Àwọn akẹ́kọ ilé ẹ̀kọ́ gíga nípinlẹ̀ ọ̀yọ́ lówurọ̀ òní péjọ sílé isẹ́ ìjọba àpapọ̀ láti fẹ̀húnúhàn lórí bí ìyansẹ́lódì ẹgbẹ́ àwọn olùkọ́ ilé ẹ̀kọ́ gíga ASUU, tise múkí wọn wà nílé fúngbà pípẹ́. Àwọn akẹ́kọ náà tí wọ́n gbé àkọlé oníruru lọ́wọ́ ni wọ́n dí ẹnu ìloro ilé isẹ́ ọ̀ún. Akọ̀ròyìn ilé isẹ́ Radio Nigeria […]Continue Reading