Home Posts tagged Jehovah Witnesses
Yoruba

Àwọn Ẹléri Jèhófà Sí Gbọ̀gàn Ìpàdé Wọn Padà

Àwọn ẹlẹ́ri Jèhófà nílẹ̀ yí àti káàkiri àgbáyé ni wọn yio si gbọ̀gàn ìpàdé wọn padà lọ́jọ́ ẹtì ọ̀sẹ̀ yí lẹ́yìn tí wọ́n ti gbéè tì padà fún bíì ọdún méjì níbamu pẹ̀lú ìlànà áàbò àti dènà ìtànkálẹ̀ àrùn covid 19. Àtẹ̀jáde látọ̀dọ̀ olú ile isẹ́ àwọn ẹlẹ́ri Jèhóvàh sọ wípé àkànseàsọyé ọlọ́gbọ̀n Continue Reading