Home Posts tagged Mọ́sálásí Oluyọle
Yoruba
Imaam àgbà Mọ́sálásí Oluyọle, Sheik Mudasiru Badda ti lon ńfẹ́ káwọn èèyàn àwùjọ máà sọ́raséè, torípé ẹ̀dá kan ọmọ ìgbà àti àkọ́kọ́ tí wọ́n yóò kun lóòkè èpẹ̀. Imam Baddah sọ èyí níbi ètò adua ogójì ọjọ́ Gómìnà tẹ́lẹ̀ nípinlẹ̀ ọ̀yọ́, Sẹ́nátọ̀ Ishaq Abiola Ajimọbi. Ó sàlàyé pé, Sẹnetọ Ajimọbi gbé ìgbé-ayé tóò làmìlaka tófimọ́ […]Read More...
Load More