Home Posts tagged Moshood Abiọla
Yoruba
Gẹ́gẹ́ bí ara áyan láti mú àgbéga bá ìmọ̀ ẹ̀rọ àtètò isẹ́ ọwọ́ lórílẹ̀dè yíì ìjọba ìpínlẹ̀ Ògùn ti fọwọ́sí gbígba oyè ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ nípa ìmọ̀ ẹ̀rọ, B.Tech nílé ẹ̀kọ́ gbogbonìse Poly Moshood Abiọla tó wà nílu Abẹokuta, Mapoly. Gómìnà ìpínlẹ̀ náà, ọmọba Dapọ Abiọdun sọ nínú ìwé tó kọ ránsẹ́ sí alákoso fétò ẹ̀kọ́, […]Read More...
Load More