Home Posts tagged Mr. Abdulwaheed Odusile
Yoruba

Ìpínlẹ̀ Ògùn Bẹ̀rẹ̀ Ètò Ayẹyẹ Òmìnira Ọdún Kọkàlélọgọ́fà Ilẹ̀ Yí

Ọkan òjòkan ètò láti sàmì ayẹyẹ ọdún kọkànlélọ́gọ́ta tílẹ̀ yí gba òmìnira ló ti bẹ̀rẹ̀ nípinlẹ̀ Ògùn lóni pẹ̀lú àkànse ìrun Jímọ̀h. Alákoso fọ́rọ̀ Ìròyìn àti Ìlànà, Ọ̀gbẹ́ni Abdulwaheed Odusile ló sọ̀rọ̀ yí di mímọ̀ nínú àtẹ̀jáde tí ó fi síta tó ní àkànse ìrun jimọh náà ló ti bẹ̀rẹ̀ ní Continue Reading