Home Posts tagged Musulumi
Yoruba

Ìjọba àpapọ̀ kéde ọjọ́ ìsẹ́gun àti ọjọ́rú tónbọ̀ gẹ́gẹ́bí ìsimi lẹ́nu isẹ́ láti sọdún iléyá

Ìjọba àpapọ̀ ti kéde ọjọ́ ìsẹ́gun Tuesday àti ọjọ́rú Wednesday ọ̀sẹ̀ tónbọ̀ gẹ́gẹ́bí ìsinmi lẹ́nu isẹ́ láti le sọdún iléyá tọdún yi. Ọrọ yí lówà nínú àtẹ̀jáde èyí tí àkọ̀wé àgbà sí alákoso lórí ọ̀rọ̀ abẹ́lé, ọ̀mọ̀wé Shuaib Belgore fisíta, pẹ̀lú àtọ́kasí pé alákoso fọ́rọ̀ abẹ́lé Rauf Arẹgbẹsọla ló kéde ohun, lórúkọ ìjọba àpapọ̀ nílu […]Continue Reading