Home Posts tagged nípinlẹ̀ Ògùn
Yoruba

Àwọn ọ̀dọ́ yarí kanlẹ̀ nípinlẹ̀ Ògùn wọ́n ní dandan kí kọ̀lọ̀pa fòpin sí fìyàjẹ ni

Àwọn ọ̀dọ́ tó ń se ìfẹ̀húnúhàn tako ikọ̀ ọlọ́pa SARS nípinlẹ̀ Ògùn ti fẹ̀sùn kan àwọn ọmọ ikọ̀ ọlọ́pa náà tíjọba ti fòfindè sí ń dúnkokò mọ́ àwọn èèyàn kan nípinlẹ̀ náà. Àwọn ọ̀dọ́ tó ń fẹ̀húnú hàn náà tí wọ́n se ìwọ́de wọ́ọ̀rọ́ wọ́ lọ sí ọ́fìsì Gómìnà nílu Abẹokuta tún fi ilodi sí […]Continue Reading