Home Posts tagged ọ̀gbẹ́ni Babatunde Fashọla
Yoruba

Ìjọba àpapọ̀ gùnlé isẹ́ òpópónà méje nílẹ̀ yí

Ìgbìmọ̀ alásẹ ìjọba àpapọ̀ ti buwọ́lu owó tó lé ní áàdọ́jọ billiọnu naira fún síse àwọn òpópónà méje káàkiri ilẹ̀ yí. Alákoso fọ́rọ̀ isẹ́ òde àti ilégbe, ọ̀gbẹ́ni Babatunde Fashọla ló sọ̀rọ̀ lórí àbájáde ìpàdé wọn nílu Abuja. Alákoso ní àwọn ọ̀nà náà yíò pèsè isẹ́ fún àwọn ẹgbẹ̀rún mẹ́ta Continue Reading