Home Posts tagged Ọgbẹni Gbajabiamila
Yoruba

Ilé asòfin kejì bèrè fájọsepọ̀ àwọn tọ́rọkàn lórí àbá òfin tóníse pẹ̀lú pẹtirolu

Adarí ilé ìgbìmọ̀ asòfin kejì, ọ̀gbẹ́ni Fẹmi gbajabiamila ti rọ àwọn akọ́sẹ́mọsẹ́ lẹ́ka afẹ́fẹ́, Gas láti sisẹ́ papọ̀ pẹ̀lù ìjọba fún ìdàgbàsókè ẹ̀ka ọ̀hún, lọ́nà àtijẹ́ kò so èso rere. Ọgbẹni Gbajabiamila ló gbọrọ àmọ̀ràn yíì kalẹ̀ lákokò ikọ̀ asojú kan látile se tón ri sọ́rọ̀ afẹ́fẹ́ Gas Continue Reading