Home Posts tagged ọ̀gbẹ́ni Kẹhinde Ayinla
Yoruba

Iná se ọsẹ́ lọ́jà Agbeni

Kò dín ní ilé ìtàjà mẹ́rin tó jóná lówurọ̀ òní lágbóòlé Jámọjẹ ní Agbéní nílu ìbàdàn nínú ìjàmbá iná èyítí ó bẹ́ sílẹ̀ ní kùtù kùtù áàrọ yi, tí gbogbo ìsápá àwọn olùgbé agbègbè náà àti àwọn òntàjà láti paná ohun jásí pàbó. Akọ̀ròrìn ilésẹ́ Radio Nigeria jábọ̀ pé títẹ̀lé dé ti àwọn òsìsẹ́ Continue Reading