Home Posts tagged Ọ̀gbẹ́ni Mohammed Manga
Yoruba
Ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀dè yíì ti kéde ọjọ́ ẹtì ọ̀sẹ̀ yíì àtọjọ́ ajé ọ̀sẹ̀ tónbọ̀ gẹ́gẹ́ bí ọjọ́ ìsinmi lẹ́nusẹ́, láti fi sàmì ayẹyẹ ọdún àjínde, fún tọdún yíì. Alákoso f’ọ́rọ̀ Abẹ́lẹ́, Ọ̀gbẹ́ni Rauf Arẹgbẹsọla ló kéde bẹ́ẹ̀ lórúkọ ìjọba àpapọ̀ nínú àtẹ̀jáde kan t’ólùdarí fétò ìròyìn àtọ̀rọ̀ tójẹmọ́ tàwùjọ nílésẹ náà, Ọ̀gbẹ́ni Mohammed Manga, fisita. […]Read More...
Load More