Omo ile asofin ipinle Oyo kan ton soju ekun gusu Ibarapa ati aringbun gun, Ogbeni Peter Oyedokun nfe ki amugboro deba, awon nkan amayederun ati owonaa toto fun Ile Eko, Olukoni Agba tipinle Oyo, to wa ni Lanlate. Nigba ton gbe aba ti kale, Continue Reading