Home Posts tagged ọ̀gbẹ́ni Shina Olukọlu
Yoruba
Alákoso fún ilésẹ́ ọlapa nípinlẹ̀ Ọyọ, ọ̀gbẹ́ni Shina Olukọlu ti sèlérí fáwọn èyàn Òkè-Ògùn pé ètò àbò tó múnádóko yó wà fún ẹ̀mí àti dúkia àwọn èyàn agbègbè náà. Ọgbẹni Olukolu ló sèlérí yi nílu Saki, lásìkò tó sàbẹ̀wò ẹnusẹ́ ságbègbè náà, tó sì késí àwọn olùgbé láti jẹ́ kámugbòrò bá ìbásepọ̀ lálafìa. Bẹ́ẹ̀ lótún […]Read More...
Load More