Home Posts tagged olùkọ́ ilé-ìwé aládani
Yoruba

Ìjọba àpapọ̀ ti ń gbèrò láti sàtìlẹyìn fún ìlànà sìsanwó àwọn olùkọ́ ilé-ìwé aládani

Igbákejì àarẹ orílẹ̀dè yíì, ọ̀jọ̀gbọ́ Yẹmi Ọsinbajo sọpé, ìjọba àpapọ̀ ti nì óuń yóò sàtìlẹyìn fún ìlànà sìsanwó osù àwọn olùkọ́ ilé-ìwé aládaní àtàwọn onísẹ́ ọwọ́, láti pinwọ́ ipá tí ìtànkálẹ̀ àrùn covid-19 timì lórí ètò ọrọ̀ ajé wọn. Níbi ètò àpérò ọlọ́dọọdún tẹ́gbẹ́ àwọn agbẹjọ́rò tónlọ Continue Reading