Home Posts tagged Osun State @30
Yoruba

Gómìnà Oyetọla Bèèrè Fún Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Gbogbo Ènìyàn

Àwọn méjìdínlọ́gbọ̀n ni wọ́n ti fàmì ẹ̀yẹ dá lọ́lá láti sàmì ayẹyẹ ọgbọ̀n ọdún ìdásílẹ̀ ìpínlẹ̀ Ọsun. Diẹ lára àwọn tí wọ́n fàmì ẹ̀yẹ dá lọ́lá náà lati rí alábojútó àgbà ìjọ ìràpadà Kristi, Àlúfà Enoch Adeboye, olórí àwọn ọmọ ológun tẹ́lẹ̀, Ọ̀gágun fèyìntì Alani Akinrinade, Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọsun Continue Reading