Home Posts tagged owó sísan
Yoruba

Bánki àpapọ̀ ilẹ̀ yíì, CBN, sàgbékalẹ̀ ìlànà ẹ̀rọ atètè dánhun sọ̀rọ̀ owó sísan

Ilé ìfowópamọ́ àpapọ̀ ilẹ̀ yíì CBN, ti sí sísọ lójú ìlànà ẹ̀rọ ìsanwó kan èyí tíwọ́n yóò tètè máà dánhun sáwọn ọ̀rọ̀ tóníse pẹ̀lú owó sísan léyi tí yóò lọ́wọ́ àwọn tón gbéjáde àtàwọn olùkópa min-in lórílẹ̀dè yíì látiridájú pé wọ́n ń sàmúlò ìlànà ọ̀hún. Ilé ìfowópamọ́ àpapọ̀ náà sọ́ọ̀di mímọ̀ Continue Reading