Home Posts tagged Oyo Police Command
Yoruba

Àwọn ikọ̀ alábo pawọ́pọ̀ láti wójùtú sí ètò àbò tó mẹ́hẹ nípinlẹ̀ Ọ̀yọ́

Ilé isẹ́ ọlọ́pa nípinlẹ̀ Ọ̀yọ́ àti àjọ ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́, DSS, ti tẹnumọ́ ìpinu wọn láti fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú àjọ áàbò araẹni láàbò ìlú, NSCDC, láti wá ojútu sí ìsoro ọ̀rọ̀ ààbò àti àwọn ìwà ọ̀daràn nípinlẹ̀ yí. Ọga àgbà ilé isẹ́ ọlọ́pa nípinlẹ̀ Ọ̀yọ́ arábìnrin Ngozi Ọnadẹkọ àti akẹgbẹ́ rẹ̀ ọ̀gá àjọ DSS, arábìnrin Clara Onika ló […]Continue Reading
Yoruba

Ọwọ́ Ilésẹ́ Ọlọ́pa Nípinlẹ̀ Ọ̀yọ́ Tẹ Àwọn Jàndùkú Agbébọn Nílu Ìgàngàn

Ilésẹ́ ọlọ́pa n’ípinlẹ̀ Ọ̀yọ́ tifìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé, ọwọ́ ti tẹ àwọn jàndùkú agbébọn mẹ́tàdínladọta nílu Ìgàngá n’ípinlẹ̀ Ọ̀yọ́. Àwọn jàndùkú agbébọn ọ̀hún lọwọ́ àwọn ikọ̀ alábo tó ńgbogun ti ìwà ọ̀daràn, “Operation Burst” tẹ́ẹ̀. Àwọn jàndùkú ọ̀hún t’ọ́wọ́ sìkún àwọn agbofinro tẹ́ẹ̀ pẹ̀lú ìbọn àtàwọn ohun ìjà olóró min lọ́wọ́ wọn, niwọ́n f’ọwọ́ òfin […]Continue Reading