Home Posts tagged Oyo REC
Yoruba

Àjọ INEC Bẹ̀rẹ̀ Àfihàn Àkọsílẹ̀ Orúkọ Olùdìbò Nípinlẹ̀ Ọ̀yọ́

Àjọ elétò ìdìbò ilẹ̀yí, INEC, ẹ̀ka tìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ti bẹ̀rẹ̀ sísàfihàn àkọsílẹ̀ orúkọ àwọn olùdìbò tuntun káàkiri àwọn ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́tẹ̀ẹ̀tàlélọ́gbọ̀n tó wà nípinlẹ̀ yí. Àkọsílẹ̀ olùdìbò tuntun yi ló jẹ́ ti àwọn tí wọ́n sẹ̀sẹ̀ forúkọ sílẹ̀ nínú ìpele àkọ́kọ́ ìforúkọ sílẹ̀ olùdìbò tọdún 2021 Continue Reading