Home Posts tagged P.T.F
News Yoruba

Àjọ P.T.F Sèkìlọ̀ Lórí Oun Tólè Fáà Ìbẹ́sílẹ̀ Àrùn Covid-19 ẹlẹketa

Ikọ̀ amúsẹ́yá ìjọba àpapọ̀ fárùn covid 19 ti sèkìlọ̀ fáwọn èèyàn ilẹ̀ yíì, láti ma kíyesara kí ilẹ̀ Nàijírìa má ba kojú àrùn covid-19, fún ìgbà kẹta. Akọ̀wé ìjọba àpapọ̀ títún se alága ikọ̀ amúsẹyá ìjọba àpapọ̀ fárùn covid-19, P.T.F, ọ̀gbẹ́ni Boss Mustapha ẹnitó sọ̀rọ̀ ìkìlọ̀ yíì nílu Abuja, Continue Reading