Home Posts tagged Philip Bankọle
Yoruba

Ẹgbẹ́ Àwọn ọmọ Ilẹ̀ Yí Nílẹ̀ Òkèèrè Bèèrè Fátìlẹyìn Ìjọba Lórí Àwọn Akẹ́kọ Tó Sá Kúrò Ní Ukraine

Alága ẹgbẹ́ àwọn ọmọ ilẹ̀ Nàijírìa lókèèrè, ẹ̀ka ti orílẹ̀ èdè Hungary, ọ̀mọ̀wé Hussaini Argungun ti bèèrè fún àtìlẹyìn ilésẹ́ ìjọba àpapọ̀ fọ́rọ̀ amujo ìjàmbá àti mímú ìdẹ̀rùn bá ará ìlú lórí àwọn akẹ́kọ ọmọ olẹ̀yí tí wọ́n sá kúrò ní Ukraine kí wọ́n báà le dúró ní Hungary. Ọmọwe Argungun ẹnití Continue Reading