Home Posts tagged Sẹnatọ Ali Ndume kéjì
Yoruba

Ilé ìgbìmọ̀ asòfin buwọlu àbá òfin lórí ètò àbò

Ilé ìgbòmọ̀ asòfin ti buwọlu àtúnse àbá òfin tọdún 2021 fún ìlànà ètò ìdìbò. Ilé dá àbá lílò ojú òpó ayélujára fi kéde èsì ìbò nu, pẹ̀lú àtọ́kasí pé kò sí opo ayálujára kárí orílẹ̀èdè Nàijírìa. Àtúnse àbá ọ̀hún ní Sẹnatọ Ali Ndume kéjì. Sẹnatọ Sabi Abdulahi àti Ali Ndume tẹnumọ pé lilo òpó Continue Reading