Home Posts tagged TETFUND
Yoruba

Àjọ TETFUND Fọwọ́ Owó Ìrànwọ́ Ise Ìwadi Billiọnu Mẹ́wa Náira Fọ́dún 2022 Sọ̀yà

Àjọ tó rísí owó ìrànwọ́ àwọn ilé ẹ̀kọ́ gíga TETFUND ti fi ìrètí hàn, wípé, owó ti yóò jẹ́ yíyá sóòtó gẹ́gẹ́ bí owó ìrànwọ́ isẹ́ ìwádi fọ́dún 2022 yóò tóò billiọnu mẹ́wa naira. Akọ̀wé àgbà àjọ TETFUND, Ọ̀jọ̀gbọ́n Suleiman Bogoro níì ìgbìmọ̀ alásẹ àjọ ohun buwọlu owó tó léní billiọnu mẹ́jọ náira gẹ́gẹ́ bí […]Continue Reading
Yoruba

Àbá Òfin Kan Tóníse Pẹ̀lú Àtúnse Òfin Àjọ TETFUND Ọdún 2007, Ti Di Kíkà Fún Ìgbàkejì Nílé Asòfin Àgbà

Wọ́n ti ka àbá òfin kan tó níse pẹ̀lú síse àtúnse sí òfin àjọ tón fowo se agbátẹrù ètò ẹ̀kọ́ láwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga, tamọ̀sí Testfund tọdún 2007 fún igbákejì nílé ìgbìmọ́ asòfin àgbà. Asòfin tón sojú ẹkùn ìdìbò àarin gbùngbùn Èkìtì, Sẹnatọ Micheal Ọpẹyẹmi Bamidele ló sagbátẹrù àbá òfin náà, tó si ń bèerè fún […]Continue Reading