
Níbàyí náà, kò ti si àisàn ibà pọ́njú ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ tàbí nílé ìwòsàn ẹ̀kẹ́sẹ́ ìsègùn UCH, nílu Ìbàdàn. Ọga àgbà ilé ìwòsàn náà, Ọ̀jọ̀gbọ́n Jesse Ọtẹgbayọ ló sọ̀rọ̀ yí níbi ìpàdé oníròyìn tó wáyé nílu Ìbàdàn. Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọtẹgbayọ ẹnití ó sàlàyé wípé àisàn yí ló wọ́pọ̀ ní áàrin gùngùn ilẹ̀ yí ìpínlẹ̀ Edo àti […]Read More...