News

Ilésésẹ́ ọlọ́pa sọ àsọyán lórí ẹgbẹ olọ́kóèrọ ìpínlẹ̀ Ọyọ

Ilésẹ́ ọlọ́pa ẹ̀ka ìpínlẹ̀ Ọyọ, sọ pé òn òní ìbásepọ̀ kankan pẹ̀lú ẹgbẹ́ tó jáde láti ìnu ẹgbẹ́ awakọ̀ nílẹ̀ yi NURTW.

Alákoso fún ilésẹ́ ọlọ́pa, ọ̀gbẹ́ni Shina Olukọlu ló sọ̀rọ̀ yí nílu’bàdàn lásìkò tó ńsọ̀rọ̀ lórí awuyewuye tón lọ lọ́wọ́ pé olúlesẹ́ ọlọ́pa ni ó ti gba káwọn igun kan látinú ẹgbẹ́ NURTW, ma sàmúlò àwọn ibùdókọ̀ kan nílu’bàdàn.

Ọgbẹni Olukolu sọpé ọwọ́ titẹ àwọn kan, tí wọ́n sì bá, on ìjà olóró tó fimọ́ ògùn ìbílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn tí wọ́n fura sí ti wọ́n gbe náà óní àwọn òsìsẹ́ nílesẹ́ ọlọ́pa kòní jáfara nípa fífi ìyà tótọ́ jẹ ẹnikẹ́ni tàbí ẹgbẹ́ tóbá ńda omi àláfìa ìpínlẹ̀ Ọyọ rú.

Makinde/Ogunkọla

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *