November 26, 2020
Home Archive by category News

News

Sport
The former Argentina attacking midfielder and manager suffered a heart attack at his Buenos Aires home.He had successful surgery on a brain blood clot earlier in November and was to be treated for alcohol dependency.Maradona was captain when Argentina won the 1986 World Cup, scoring the famous ‘Hand of God’ goal against England in the […]Read More...
Energy
Ogun State House of Assembly has called for the removal of electricity generation and distribution from the exclusive legislative list to the concurrent list with a view to ensuring the establishment of energy system by the state government. Speaker of the house of Assembly Mr. Olakunle Oluomo, made the appeal at a Public forum on a proposed bill  […]Read More...
News Yoruba
Ètó ìpolongo àti ìlanilọ́yẹ̀ lórí fífòpinsí ètò abẹ-dídá fọ́mọbìrin nípinlẹ̀ ọ̀yọ́ lóti sọ èso rere pẹ̀lú bí agbègbè mẹ́rìndínlógójì nìjọba ìbílẹ̀ Ìsẹ́yìn nípinlẹ̀ ọ̀yọ́, se fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé àsà náà tidi ohun àfìsẹ́yìn téegún fisọ. Èyí tẹlẹ oníruru ètò ìdánilẹ́kọ àti ìpàdé pẹ̀lú àwọn tọ́rọkàn lórí abẹ-dídá, èyítí àjọ olùtanijí sojuse ẹni N.O.A nípinlẹ̀ […]Read More...
News Yoruba
Ẹgbẹ́ àwọn obìnrin oníròyìn nílẹ̀ Nàijírìa, NAWOJ, ẹ̀ka tìpínlẹ̀ Ọsun, ti késìjọba àtàwọn àjọ tí kíì se tìjọba láti fọwọ́sowọ́pọ̀ lẹ́nu ìgbésẹ̀ fífòpinsí ọ̀kanọ̀jọ̀kan ìwà ipá àti ìkọlù tó ń kojú àwọn obìnrin. Níbi ètò àyájọ́ ọjọ́ fífòpinsí gbogbo àwọn ìkọlù tón kojú àwọn obìnrin, niwọ́n ti fìdí èyí múlẹ̀. Alága ẹgbẹ́ NAWOJ, ẹ̀ka tìpínlẹ̀ […]Read More...
News Yoruba
Igbákejì àarẹ ille yíì, ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmi Ọsinbajo sọ pé, ìjọba àpapọ̀ ti ń sisẹ́ pẹ̀lú ilé ìfowópamọ́ àpapọ́ orílẹ̀dè yíì, CBN, fún isẹ́ akoyawo àti níní ànfàní si síse pàsí pàrọ̀ owó ilẹ̀ òkèrè pọ̀ọsi. Nígbà tó ń báwọn adarí olókoowò nílẹ̀ faransé sọ̀rọ̀ nílu Abuja, lọ̀jọ̀gbọ́n Ọsinbajo ti sọ́ọdi mímọ̀ pé, ìjọba ń sakitiyan […]Read More...
Load More